Máàkù 4:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi, wọ́n sì wí fún ara wọn pé, “Irú ọkùnrin wo ni èyí, tí ìjì àti òkun ń gbọ́ tirẹ̀!”

Máàkù 4

Máàkù 4:39-41