Máàkù 4:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dìde, ó bá ìjì líle náà wí, ó sì wí fún òkun pé, “Dákẹ́ jẹ́ẹ́,” ìjì náà sì dá, ìparọ́rọ́ ńlá sì wà.

Máàkù 4

Máàkù 4:36-41