Máàkù 4:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìji líle ńlá kan sì dìde, omi sì ń bù sínú ọkọ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí ọkọ̀ fi bẹ̀rẹ̀ síi kún fún omi, ó sì fẹ́rẹ rì.

Máàkù 4

Máàkù 4:36-38