Máàkù 4:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ilẹ̀ kọ́kọ́ hù èso jáde fún ara rẹ̀, ó mú èéhù ewé jáde, èyí tí ó tẹ̀lé e ni orí ọkà, ní ìparí, ọkà náà gbó.

Máàkù 4

Máàkù 4:27-30