Máàkù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jésù sì wọ inú ilé kan, àwọn ẹ̀rọ̀sì tún kórájọ, tó bẹ́ẹ̀ tí Òun àti àwọn Ọmọ-ẹ̀yin rẹ̀ kò rí ààyè láti jẹun.

Máàkù 3

Máàkù 3:15-30