Máàkù 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Díẹ̀ nínú àwọn Farisí wí fún Jésù pé, “Wò ó, è é ṣe ti wọn fi ń ṣe èyí ti kò yẹ ni ọjọ́ ìsinmi.”

Máàkù 2

Máàkù 2:20-28