Máàkù 15:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnú ya Pílátù láti gbọ́ pé Jésù ti kú. Nítorí náà ó pe balógun-ọ̀rún, ó sì bí i léèrè bóyá Jésù ti kú ní tòótọ́.

Máàkù 15

Máàkù 15:37-47