Máàkù 14:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì mú un yín lọ sí gbàngàn ńlá kan lókè ilé náà, tí a ti ṣe lọ́sọ́. Níbẹ̀ ni kí ẹ pèṣè sílẹ̀ dè wá.”

Máàkù 14

Máàkù 14:12-23