Máàkù 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú wọn dùn láti gbọ́ èyí, wọ́n sì pinnu láti fún un ní owó. Nítorí náà ó bẹ̀rẹ̀ sí í sọ àkókò tí ó rọrùn tí òun yóò fi Jésù lé wọn lọ́wọ́.

Máàkù 14

Máàkù 14:5-13