Máàkù 13:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Arákùnrin yóò máa fi ẹ̀sùn kan arákùnrin rẹ̀, tí yóò sì yọrí sí ikú. Baba yóò máa ṣe ikú pa ọmọ rẹ̀. Àwọn ọmọ yóò máa dìtẹ̀ sí òbí wọn. Àní, àwọn ọmọ pẹ̀lú yóò máa ṣekú pa òbí wọn.

Máàkù 13

Máàkù 13:5-17