Máàkù 12:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó sọ fún wọn wí pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yin pé, tálákà opó yìì sọ sínú àpótí ìsura ju gbogbo àwọn ìyókù lọ to sọ sínú rẹ lọ.

Máàkù 12

Máàkù 12:34-44