Máàkù 12:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùkọ́ ófin náà dáhùn pé, “Olùkọ́, ìwọ sọ òtítọ́ nípa pé Ọlọ́run kan ní ó ń bẹ, àti pé kò sí òmíràn àfi òun nìkan.

Máàkù 12

Máàkù 12:25-36