Máàkù 12:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí a fẹ́ mọ̀ nìyì: Níwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé àwọn arákùnrin méjèèje ló fẹ́ obìnrin náà, ìyàwó o ta ni yóò jẹ́ nínú wọn lọ́jọ́ àjíǹde?”

Máàkù 12

Máàkù 12:20-28