Máàkù 12:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Arákùnrin rẹ̀ kejì ṣu obìnrin tí ó fi sílẹ̀ lópó, láìpẹ́, òun pẹ̀lú tún kú láìbímọ. Arákùnrin kẹta tó sú obìnrin yìí lópó tún kú bákan náà láìbímọ.

Máàkù 12

Máàkù 12:18-22