Máàkù 12:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Olùkọ́, Mósè fún wa ní òfin pé: Nígbà tí ọkùnrin kan bá kú láìbí ọmọ, arákùnrin rẹ̀ gbọdọ̀ ṣú ìyàwó náà lópó kí wọn sì bímọ ní orúkọ ọkọ tí ó kú náà.

Máàkù 12

Máàkù 12:18-23