Máàkù 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wà láàrin ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn níwájú, lẹ́yìn, gbogbo wọn sì ń kígbe wí pé,“Hòsánà!”“Olùbùkún ni ẹni náà tí ó ń bọ̀ wà ní orúkọ Olúwa!”

Máàkù 11

Máàkù 11:8-14