Máàkù 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà tí ẹ bá ń gbàdúrà, ẹ kọ́kọ́ dáríjì ẹni tí ó ṣẹ̀ yín. Baba yín lọ́run yóò dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tiyín náà jì yín.”

Máàkù 11

Máàkù 11:19-26