Máàkù 11:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà, bí ìṣe wọn, Jésù àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ jáde kúrò ní ìlú Jerúsálémù.

Máàkù 11

Máàkù 11:12-22