Máàkù 10:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ni ìwọ fẹ́ kí èmi kí ó ṣe fún ọ?”Afọ́jú náà dáhùn pé, “Rábì, jẹ́ kí èmi ki o ríran.”

Máàkù 10

Máàkù 10:45-52