Máàkù 10:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí, Èmi, Ọmọ ènìyàn kò wá sí ayé kí ẹ lè ṣe ìránṣẹ́ fún mi, ṣùgbọ́n láti lè ran àwọn ẹlòmíràn lọ́wọ́, àti láti kú fún ìràpadà ọ̀pọ̀ ènìyàn.”

Máàkù 10

Máàkù 10:39-46