Máàkù 10:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù wò wọ́n? ó sì wí fún wọn pé, “Ènìyàn ní èyí kò se é ṣe fún ṣùgbọ́n kì í ṣe fún Ọlọ́run, nítorí ohun gbogbo ni síṣe fún Ọlọ́run.”

Máàkù 10

Máàkù 10:17-31