Máàkù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù dé, ẹni tí ó ń tẹnibọmi ní ihà, tí ó sì ń wàásù ìtẹ̀bọmi ìrònúpìwàdà fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀.

Máàkù 1

Máàkù 1:2-6