Máàkù 1:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, kí ilẹ̀ tó mọ́, Jésù nìkan jáde lọ sí ihà kan, láti lọ gbàdúrà.

Máàkù 1

Máàkù 1:32-44