Máàkù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àsìkò náà gan-an ni ọkùnrin kan tí ó wà nínú sínágọ́gù wọn, tí ó ní ẹ̀mí àìmọ́, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í kígbe wí pé,

Máàkù 1

Máàkù 1:20-29