Lúùkù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hẹ́rọ́dù sì wí pé, “Jòhánù ni mo ti bẹ́ lórí: ṣùgbọ́n tani èyí tí èmi ń gbọ́ irú nǹkan wọ̀nyí sí?” Ó sì ń fẹ́ láti rí i.

Lúùkù 9

Lúùkù 9:3-10