Lúùkù 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hẹ́rọ́dù tẹ́tírákì sì gbọ́ nǹkan gbogbo èyí tí a ṣe láti ọ̀dọ̀ rẹ̀ wá: ó sì dààmú, nítorí tí àwọn ẹlòmíràn ń wí pé, Jòhánù ni ó jíǹde kúrò nínú òkú;

Lúùkù 9

Lúùkù 9:4-10