Lúùkù 9:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ọmọ ènìyàn kò wá láti pa ẹ̀mí ènìyàn run, bí kò ṣe láti gbà á là. Wọ́n sì lọ sí ìletò mìíràn.

Lúùkù 9

Lúùkù 9:55-60