Lúùkù 9:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ósì rán àwọn ìránṣẹ́ lọ sí iwájú rẹ̀: nígbà tí wọ́n sì lọ wọ́n wọ ìletò kan tí í ṣe ti ará Samaríà láti pèṣè sílẹ̀ dè é.

Lúùkù 9

Lúùkù 9:46-53