Lúùkù 9:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu sì ya gbogbo wọn sí iṣẹ́ ọláńlá Ọlọ́run, ṣùgbọ́n nígbà tí hà sì ń ṣe gbogbo wọn sí ohun gbogbo tí Jésù ṣe, ó wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ pé,

Lúùkù 9

Lúùkù 9:39-52