Lúùkù 9:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì dáhùn pé, “Ìran aláìgbàgbọ́ àti àrékérekè, èmi ó ti bá yín gbé pẹ́ tó? Èmi yóò sì ti ṣe sùúrù fún yín pẹ́ tó? Fa ọmọ rẹ wá níhín-ín yìí.”

Lúùkù 9

Lúùkù 9:35-50