Lúùkù 9:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ilékílé tí ẹ̀yin bá sì wọ̀, níbẹ̀ ni kí ẹ̀yin gbé, láti ibẹ̀ ni kí ẹ̀yin sì ti jáde.

Lúùkù 9

Lúùkù 9:1-10