Lúùkù 9:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì kíyèsí i, ẹ̀mí ẹ̀sù a máa mú un, a sì máa kígbe lójijì; a sì máa nà án tàntàn títí yóò fi yọ ìfófòó lẹ́nu, a máa pa á lára, kì í tilẹ̀ ń fẹ́ fi í sílẹ̀ lọ.

Lúùkù 9

Lúùkù 9:35-47