Lúùkù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì bi wọ́n pé, “Ṣùgbọ́n tani ẹ̀yin ń fi èmi pè?”Pétérù sì dáhùn, wí pe, “Kírísítì ti Ọlọ́run.”

Lúùkù 9

Lúùkù 9:13-22