Lúùkù 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Afúrúgbìn kan jáde lọ láti fún irúgbìn rẹ̀: bí ó sì ti ń fúrúgbìn, díẹ̀ bọ́ sí ẹ̀bá ọ̀nà, a sì tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ṣà á jẹ.

Lúùkù 8

Lúùkù 8:3-12