Lúùkù 8:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wá sí ẹ̀yìn rẹ̀, ó fi ọwọ́ tọ́ ìṣẹ́tí aṣọ rẹ̀; lọ́gán ni ìsun ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sì ti gbẹ.

Lúùkù 8

Lúùkù 8:43-54