Lúùkù 8:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbo ẹlẹ́dẹ̀ púpọ̀ sì ń bẹ níbẹ̀ tí ń jẹ lórí òkè: wọ́n sì bẹ̀ ẹ́ kí ó jẹ́ kí àwọn wọ inú wọn lọ. Ó sì yọ̀ǹda fún wọn.

Lúùkù 8

Lúùkù 8:22-41