Lúùkù 8:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì bí i pé, “Orúkọ rẹ?” Ó sì dáhùn pé,“Léjíónì,” nítorí ẹ̀mí ẹ̀ṣù púpọ̀ ni ó ti wọ̀ ọ́ lára lọ.

Lúùkù 8

Lúùkù 8:27-31