Lúùkù 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí kò sí ohun tí ó farasin, tí a kì yóò fihàn, tàbí ohun tí a fi pamọ́, ti a kì yóò sì mọ̀ kí ó sì yọ sí gbangba.

Lúùkù 8

Lúùkù 8:7-18