Lúùkù 7:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Farisí kan sì rọ̀ ọ́ kí ó wá bá òun jẹun, ó sì wọ ilé Farisí náà lọ ó sì jókòó láti jẹun.

Lúùkù 7

Lúùkù 7:35-46