Lúùkù 7:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ ọ̀dọ̀ balógun ọ̀rún kan, tí ó ṣọ̀wọ́n fún un, ṣàìsàn, ó sì ń kú lọ.

Lúùkù 7

Lúùkù 7:1-5