Lúùkù 6:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn rere láti inú ìsúra rere ọkàn rẹ̀ ní mú ohun rere jáde wá; àti ènìyàn búburú láti inú ìṣúra búburú ọkàn rẹ̀ ní í mú ohun búburú jáde wá: nítorí ohun tí ó wà nínú ọkàn ni ẹnu rẹ̀ ń sọ.

Lúùkù 6

Lúùkù 6:42-49