Lúùkù 6:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ má ṣe dáni lẹ́jọ́, a kì yóò sì dá yín lẹ́jọ́: ẹ má ṣe dáni lẹ́bi, a kì yóò sì dá yín lẹ́bi: ẹ dáríjì, a ó sì dáríjì yín.

Lúùkù 6

Lúùkù 6:27-42