Lúùkù 6:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin sì ṣoore fún àwọn tí ó ṣoore fún yín, ọpẹ́ kíni ẹ̀yin ní? Àwọn ‘ẹlẹ́sẹ̀’ pẹ̀lú ń ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́.

Lúùkù 6

Lúùkù 6:27-39