Lúùkù 6:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n mo wí fún ẹ̀yin tí ń gbọ́ mi: Ẹ fẹ́ àwọn ọ̀ta yín, ṣoore fún àwọn tí ó kórìíra yín;

Lúùkù 6

Lúùkù 6:18-31