Lúùkù 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Símónì (ẹni tí a pè ní Pétérù) àti Ańdérù arákùnrin rẹ̀, Jákọ́bù àti Jòhánù, Fílípì àti Batolóméù.

Lúùkù 6

Lúùkù 6:12-20