Lúùkù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti dákẹ́ ọ̀rọ̀ í sọ, ó wí fún Símónì pé, “Tì í sí ibú, kí o sì ju àwọ̀n yín sí ìsàlẹ̀ fún àkópọ̀.”

Lúùkù 5

Lúùkù 5:3-10