Lúùkù 5:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Léfì sì ṣe àṣè ńlá kan fún Jésù ní ilé rẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn agbowó òde àti àwọn mìíràn sì ń jẹun pẹ̀lú wọn.

Lúùkù 5

Lúùkù 5:19-30