Lúùkù 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èwo ni ó yá jù: láti wí pé, ‘A dárí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ jì ọ́,’ tàbí láti wí pé, ‘Dìde kí ìwọ sì má a rìn’?

Lúùkù 5

Lúùkù 5:22-31