Lúùkù 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójú kan náà, èṣù sì mú un lọ sí orí òkè gíga, ó sì fi gbogbo ilẹ̀-ọba ayé hàn án.

Lúùkù 4

Lúùkù 4:2-12