Lúùkù 4:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Adẹ́tẹ̀ púpọ̀ ní sì ń bẹ ní Ísírẹ́lì nígbà wòlíì Èlíṣà; kò sì sí ọ̀kan nínú wọn tí a wẹ̀nùmọ́, bí kò ṣe Námánì ará Síríà.”

Lúùkù 4

Lúùkù 4:19-37